AYAAYA MO NI FUU;
AFON BA´LE RO KI.
A DIA FUN FAWOYEMI,
OMOBINRIN ORO
NWON NI O RU´BO NITORI OMO. 5
O GBO RIRU EBO, O RUU;
O GBO ERU ATUKESU, O TU;
O GBO IKARARA EBO HA FUN UN.
IJO NI NJO,
AYO NI NYO; 10
O NYIN AWON AWOO RE,
AWON AWOO RE NYIN´FA.
O NI: ILE OSUN O GBAYE O O O;
ILE OSUN O GBAYE.
OORO LA BA OSUN O; 15
ILE OSUN O GBAYE!
- - - -
- -
- - - -
- - - -
CONTATO